Jump to content

Aberdeenshire

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Aberdeenshire
Aiberdeenshire
Siorrachd Obar Dheathain

Location
Geography
Area Ranked 4th
 - Total 6,313 km2 (2,437 sq mi)
 - % Water ?
Admin HQ Aberdeen
ISO 3166-2 GB-ABD
ONS code 00QB
Demographics
Population [[List of Scottish council areas by population|Ranked Àdàkọ:Scottish council populations]]
 - Total (Àdàkọ:Scottish council populations) Àdàkọ:Scottish council populations
 - Density Àdàkọ:Scottish council populations
Politics
Aberdeenshire Council
http://www.aberdeenshire.gov.uk/
Control Àdàkọ:Scottish council control
MPs
MSPs
Aberdeenshire

Agbègbè kan ní ìlà-oòrùn Scotland ni Aberdeenshire. Ó ní àwọ òkè ní apá ìwọ̀-oòrùn rẹ̀. Ibi tí ó ga jù níbẹ̀ ni a ń pè ní Cairngorm. Àwọn òkè yìí jẹ ojú ní gbèsè. Orí òkè wọ̀nyí ni odò Don àti Dee ti sun wá. Ní apá ìlà-oòrùn Aberdenshire, iṣẹ́ àgbẹ̀ ni ó jẹ wọ́n lógún. Bí wọ́n ti ń dáko ni wọ́n ń sin nǹkan ọ̀sìn. Bèbè òkun ibẹ̀ ní òkúta. Buchan Ness tí ó wà ní Aberdeenshire ni ìlú tí ó kángun jù ní ìlà-oòrùn ilẹ̀ Scotland. Àwọn ìlú tí ó ṣe pàtàkì ní Aberdeenshire ni Aberdeen, Peterhead, fraserburgh, Inverturie, Ballatre àti Huntly. Iṣẹ́ àgbẹ̀ ni ó wọ́pọ̀ jù ní Aberdeenshire. Wọ́n dá ilé-iṣẹ́ ẹja sílẹ̀ ní Aberdeen, fraserburgh àti Peterhead. Àwọn ènìyàn ti ó wà ní agbègbè yìí ní 1961 jẹ́ 298, 503.