Althea Gibson
Ìrísí
Orílẹ̀-èdè | USA |
---|---|
Ìga | 1.80 m (5 ft 11 in) |
Ọwọ́ ìgbáyò | tennis |
Ẹnìkan | |
Iye ìdíje | 0–0 |
Grand Slam Singles results | |
Open Austrálíà | F (1957) |
Open Fránsì | W (1956) |
Wimbledon | W (1957, 1958) |
Open Amẹ́ríkà | W (1957, 1958) |
Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 0–0 |
Grand Slam Doubles results | |
Open Austrálíà | W (1957) |
Open Fránsì | W (1956) |
Wimbledon | W (1956, 1957, 1958) |
Open Amẹ́ríkà | W (1957) |
Althea Gibson (August 25, 1927 – September 28, 2003) je obinrin elere idaraya eni iye 1 lagbaye ara Amerika to je obinrin omo Afrika Amerika akoko to kopa ninu idije tenis lagbaye ati eni akoko to bori lati gba ife eye Grand Slam ni 1956. Won unpe nigba miran bi "Jackie Robinson ti tenis" nitoripe o mu opin wa si iwa "eleyameya ninu tenis."
Igbesiaye
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bi ni August 25, 1927 ni Silver, Clarendon County, South Carolina fun Daniel ati Annie Bell Gibson, Althea ni awon aburo meji, Daniel Jr. (to je mimi bi "Bubba"), ati Mildred ti se obinrin.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |