Femi Kuti
Ìrísí
Femi Kuti | |
---|---|
Photo by Tom Beetz | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Femi Anikulapo Kuti |
Ìbẹ̀rẹ̀ | London, UK/Nigeria |
Irú orin | Afrobeat, jazz |
Occupation(s) | Singer-songwriter, instrumentalist |
Instruments | Saxophone, vocals, trumpet, keyboards |
Years active | 1978 - present |
Associated acts | Egypt 80, Positive Force |
Olúfẹlá Olúfẹ́mi Aníkúlápó Kútì (ọjọ́ìbí 16 June 1962) jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria. Gbajúgbajà akọrin yí ni a mọ̀ sí Fẹ́mi Kútì. Ó jẹ́ akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí a bí ní ìlú London tí ó dàgbà sí ìlú Èkó. Ó jé àkọ́bí ọmọ ọkùnrin ọmọ bíbí olùdásílẹ̀ orin Afrobeat tí a mọ̀ sí Fẹlá Kútì àti ọmọ ọmọ akíkanjú olóṣèlú, ajá fún ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin, ìyá ààfin Olúfúnmiláyọ̀ Ransome-Kútí.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |