Jump to content

Nicolás Avellaneda

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nicolás Avellaneda
National Senator
In office
May 3, 1882 – November 25, 1885
ConstituencyTucumán
In office
May 3, 1884 – October 10, 1884
ConstituencyTucumán
Ààrẹ orile-èdè Argentina
In office
October 12, 1874 – October 11, 1880
Vice PresidentMariano Acosta
AsíwájúDomingo F. Sarmiento
Arọ́pòJulio A. Roca
Minister of Justice and Public Instruction
In office
October 12, 1868 – August 10, 1873
ÀàrẹDomingo Faustino Sarmiento
AsíwájúEduardo Costa
Arọ́pòJuan Crisóstomo Albarracín
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíOctober 3, 1837[1]
San Miguel de Tucumán, Tucumán
AláìsíNovember 24, 1885(1885-11-24) (ọmọ ọdún 48)
At sea
Ọmọorílẹ̀-èdèArgentina
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNational Autonomist Party
(Àwọn) olólùfẹ́Carmen Nóbrega Miguens[2]
ProfessionAgbẹjọro

Nicolás Remigio Aurelio Avellaneda Silva (3 October 1837 – 24 November 1885) jẹ́ ará orílè-èdèArgentine olóṣèlú ati oniróyìn, Aarẹ orile-èdè Argentina larin 1874 sí 1880.

Wọn bi Nicolás si San Miguel de Tucumán, ìyá rẹ̀ ko lọ Bolivia pẹ̀lú rẹ̀ leyin ìkú bàbá rẹ̀, Marco Avellaneda. O ka nipa ìgbẹ́jọ́rò ni Córdoba, ti o si parí ekó náà. Padà ṣí Tucumán o da El Eco del Norte sí lẹ̀, tí sì ko lọ si Buenos Aires ni ọdún 1857,ti o si di oludari El Nacional ati alatunkọ ni El Comercio de la Plata. O pari ẹ̀kọ́ re ni Buenos Aires, níbi ti o ti pade Domingo Faustino Sarmiento. Sarmiento ran lọwọ lati jẹ olùkọ́ ní University of Buenos Aires.


  1. "F. Pigna". Archived from the original on 2013-12-15. Retrieved 2010-09-28.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. NICOLÁS AVELLANEDA (1874 – 1880) | Casa Rosada