Jump to content

Yunifásítì ìlú Calabar

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Fáṣítì Ìpínlẹ̀ Calabar.
Yunifásítì ìlú Calabar

Yunifásítì ìlú Calabaryunifásítì ijoba tí o wà ní Calabar, ìpínlè Cross River, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. A da kalè ní odun 1973 [1]. Orúko olori yunifásitì náà lówólówó ni Òjògbón Florence Obi [2], Òjògbón Florence di olori yunifásitì náà ní ojó kiní, osù kejila, odun 2020 (Dec 1, 2020)[3].




  1. "University Of Calabar Nigeria". University of Calabar Nigeria. 2018-08-03. Retrieved 2022-03-03. 
  2. Uchechukwu, Ike (2021-12-02). "I will complete all abandoned projects, UNICAL VC assures". Vanguard News. Retrieved 2022-03-03. 
  3. "Vice Chancellor Florence Obi’s 100 days of transformation in UNICAL". Vanguard News. 2021-03-10. Retrieved 2022-03-04.